ARAPAREGÀNGÀN (ADESINA ABIOLA TAIWO)

ARAPAREGÀNGÀN (ADESINA ABIOLA TAIWO)

Bi obìnrin ba fi ojú di Orò
Oró a gbé!
Sango is known for his love for bàtá,
Wherever bàtá sounds kola kola
Ìjo bàtá ni won jo!

Aràpàregangan
Arewa obìnrin,
Wherever ìyá ilu echos
Aràpàregangan is never found wanted!
Ààyò gbogbo ọkùnrin
Ṣèbì wọ́n ní Olódùmarè a ṣèyí ó wùú ni
(It was said that God do whatever he wish)
Kò kú sírọ́ níbẹ̀
Olódùmarè dá Aràpàregángan pẹ̀lú ẹwà!
Kò kúkú yọ ọwọ́ ijó sẹ́yìn nínú ẹ̀bùn tí ọ́ fi ta á lọ́rẹ

Araparegangan
The sight of your dancing steps makes me a moron,
Nítorí wípé, o kọja ohùn ojú rí tí ẹnu o le so
(Because, it’s beyond mere sight seeing)
You’ve danced for the kings from the west
Wọn fun e lo’wo
(Wealth was bestowed on you by the king)
O kúkú jo fún ìjòyè, ìjòyè fún o ni ìlékè
(You also danced for the chiefs and coral beads was bestowed on you)
Aràpàregangan,
Ma jo si ibi to wu ee.

From the day i set my eyes on you
I’ve been dancing lustfully to the beat from your waist bead,
I dream of you
Dancing bàtá to my pedigree
Aràpàregángan!
Forever you will be my choice.

Akéwì: Adesina Abiola Taiwo

 519 total views,  1 views today

Author: Judaisky

Judaisky is a young writer who believes the world can only be saved PEACEFULLY through the tidings of the ink cos the pen is mightier than the sword. Do You want to know more about me, contact me 09039956005

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *